Jeremáyà 1:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wòó, mo yàn ọ́ lórí àwọn orílẹ̀ èdè àti ìjọba gbogbo láti fàtu, wó lulẹ̀, láti bàjẹ́, láti jágbà, láti má a kọ́, àti láti máa gbìn.

Jeremáyà 1

Jeremáyà 1:6-13