Jẹ́nẹ́sísì 9:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run sì súre fún Nóà àti àwọn ọmọ rẹ̀ wí pé, “Ẹ máa bí sí i, kí ẹ sì pọ̀ ní iye, kí ẹ sì kún aye.

Jẹ́nẹ́sísì 9

Jẹ́nẹ́sísì 9:1-4