Jẹ́nẹ́sísì 8:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kó gbogbo àwọn ẹ̀dá alààyè tí ó wà pẹ̀lú rẹ jáde: àwọn ẹyẹ, ẹranko àti gbogbo àwọn ẹ̀dá tí ń rìn nílẹ̀, kí wọn lè bí sí i, kí wọn sì pọ̀ sí i, kí wọn sì máa gbá yìn-ìn lórí ilẹ̀.”

Jẹ́nẹ́sísì 8

Jẹ́nẹ́sísì 8:13-18