Jẹ́nẹ́sísì 8:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Jáde kúrò nínú ọkọ̀, ìwọ àti aya rẹ, pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ àti àwọn aya wọn.

Jẹ́nẹ́sísì 8

Jẹ́nẹ́sísì 8:12-18