Jẹ́nẹ́sísì 7:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sì mú méjeméje pẹ̀lú nínú onírúurú ẹyẹ takọ tabo ni kí o mú wọn, wọlé sínú ọkọ̀ pẹ̀lú rẹ, kí á baà lè pa wọ́n mọ́ láàyè ní gbogbo ayé.

Jẹ́nẹ́sísì 7

Jẹ́nẹ́sísì 7:1-4