Jẹ́nẹ́sísì 7:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mú méjeméje nínú àwọn ẹran tí ó mọ́, akọ àti abo, mú méjìméjì takọ tabo nínú àwọn ẹran aláìmọ́.

Jẹ́nẹ́sísì 7

Jẹ́nẹ́sísì 7:1-4