Jẹ́nẹ́sísì 7:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ohun tí ó wà lórí ìyàngbẹ ilẹ̀ tó ní èémí ìyè ní ihò imú wọn ni ó kú.

Jẹ́nẹ́sísì 7

Jẹ́nẹ́sísì 7:16-23