Jẹ́nẹ́sísì 7:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ohun alààyè tí ó wà lórí ilẹ̀ parun: ẹyẹ, ohun ọ̀sìn, ẹranko igbó, àwọn ẹ̀dá afàyàfà àti ènìyàn.

Jẹ́nẹ́sísì 7

Jẹ́nẹ́sísì 7:20-24