Jẹ́nẹ́sísì 6:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì rí bí ìwà búburú ènìyàn ti ń gbilẹ̀ si, àti pé gbogbo èrò inú rẹ̀ kìkì ibi ni, ní ìgbà gbogbo.

Jẹ́nẹ́sísì 6

Jẹ́nẹ́sísì 6:1-13