Jẹ́nẹ́sísì 6:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn òmìrán wà láyé ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì, àti lẹ́yìn ìgbà náà: nígbà tí àwọn ọmọ Ọlọ́run lọ bá àwọn ọmọbìnrin ènìyàn lò pọ̀ tí wọ́n sì bímọ fún wọn. Àwọn náà ni ó di akọni àti olókìkí ìgbà náà.

Jẹ́nẹ́sísì 6

Jẹ́nẹ́sísì 6:1-6