Jẹ́nẹ́sísì 5:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àpapọ̀ ọdún rẹ̀ sì jẹ́ ẹgbẹ̀rin-ọdún-ó-dín-mẹ́talélógún (777), ó sì kú.

Jẹ́nẹ́sísì 5

Jẹ́nẹ́sísì 5:22-32