Jẹ́nẹ́sísì 5:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Lámékì pé ọdún méjìlélọ́gọ́sàn án (182) ni ó bí ọmọkùnrin kan.

Jẹ́nẹ́sísì 5

Jẹ́nẹ́sísì 5:27-32