Jẹ́nẹ́sísì 5:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Járédì pé ọmọ ọgọ́jọ-ó-lé-méjì ọdún (162) ni ó bí Énọ́kù.

Jẹ́nẹ́sísì 5

Jẹ́nẹ́sísì 5:16-25