Jẹ́nẹ́sísì 49:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ kìnnìún ni ọ́, ìwọ Júdà,o darí láti ìgbẹ́ ọdẹ, ọmọ mi.Bí i kìnnìún, o ba mọ́lẹ̀, o sì sùn sílẹ̀ bí i abo kìnnìún,Ta ni ó tó bẹ́ẹ̀, kí o lé e dìde?

Jẹ́nẹ́sísì 49

Jẹ́nẹ́sísì 49:3-18