Jẹ́nẹ́sísì 49:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Júdà, àwọn arákùnrin rẹ yóò yìn ọ,ọwọ́ rẹ yóò wà ní ọrùn àwọn ọ̀ta rẹ,àwọn ọmọkùnrin baba rẹ yóò foríbalẹ̀ fún ọ.

Jẹ́nẹ́sísì 49

Jẹ́nẹ́sísì 49:4-12