Jẹ́nẹ́sísì 46:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni orúkọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (Jákọ́bù àti Ìran rẹ̀) tí ó sọ̀kalẹ̀ lọ Éjíbítì:Rúbẹ́nì àkọ́bí Jákọ́bù.

Jẹ́nẹ́sísì 46

Jẹ́nẹ́sísì 46:2-12