Jẹ́nẹ́sísì 46:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó kó àwọn ọmọ rẹ̀ ọkùnrin pẹ̀lú àwọn ọmọ-ọmọ rẹ̀ ọkùnrin, àwọn ọmọ rẹ̀ obìnrin pẹ̀lú àwọn ọmọ-ọmọ rẹ̀ obìnrin-gbogbo irú-ọmọ rẹ̀ lọ sí Éjíbítì.

Jẹ́nẹ́sísì 46

Jẹ́nẹ́sísì 46:1-15