Jẹ́nẹ́sísì 46:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run sì bá Ísírẹ́lì sọ̀rọ̀ ní ojú ìrán ní òru pé, “Jákọ́bù! Jákọ́bù!”Ó sì dáhùn pé, “Èmi nìyí.”

Jẹ́nẹ́sísì 46

Jẹ́nẹ́sísì 46:1-3