Jẹ́nẹ́sísì 45:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ísírẹ́lì sì wí pé, “Mo gbà dájúdájú wí pé, Jósẹ́fù ọmọ mi wà láàyè. Èmi ó lọ rí i kí n tó kú.”

Jẹ́nẹ́sísì 45

Jẹ́nẹ́sísì 45:26-28