Jẹ́nẹ́sísì 44:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ha kọ́ ni kọ́ọ̀bù tí olúwa mi ń lò fún ohun mímu tí ó sì tún ń fi í ṣe àyẹ̀wò? Ohun tí ẹ ṣe yìí burú púpọ̀.’ ”

Jẹ́nẹ́sísì 44

Jẹ́nẹ́sísì 44:1-13