Jẹ́nẹ́sísì 44:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn kò tí ì rìn jìnnà sí ìlú náà tí Jósẹ́fù fi wí fún ìránṣẹ́ rẹ̀ pé, “Lépa àwọn ọkùnrin náà, nígbà tí o bá sì bá wọn, kí o wí pé, ‘Èéṣe ti ẹ fi búburú san rere.?

Jẹ́nẹ́sísì 44

Jẹ́nẹ́sísì 44:1-5