Jẹ́nẹ́sísì 43:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi fúnra mi yóò ṣe onídùúró fún un, èmi ni kí o gbà pé o fi lé lọ́wọ́. Bí n kò bá sì mu un padà tọ̀ ọ́ wá, jẹ́ kí ẹ̀bi rẹ̀ kí ó jẹ́ tèmi ní gbogbo ọjọ́ ayé mi níwájú rẹ.

Jẹ́nẹ́sísì 43

Jẹ́nẹ́sísì 43:5-17