Jẹ́nẹ́sísì 43:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Júdà sì wí fún Ísírẹ́lì bàbá rẹ̀, “Jẹ́ kí ọmọkùnrin náà lọ pẹ̀lú mi, a ó sì lọ ní kíákíá, kí àwa àti ìwọ àti àwọn ọmọ wa le yè, kí a má sì kú.

Jẹ́nẹ́sísì 43

Jẹ́nẹ́sísì 43:7-10