Jẹ́nẹ́sísì 43:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó béèrè àlàáfíà wọn, ó sì wí pé, “Ṣé àlàáfíà ni baba yín wà, baba arúgbó tí ẹ sọ̀rọ̀ rẹ̀ fún mi, ṣé ó sì wà láàyè?”

Jẹ́nẹ́sísì 43

Jẹ́nẹ́sísì 43:25-33