Jẹ́nẹ́sísì 43:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Jósẹ́fù dé sí ilé, wọ́n kó àwọn ẹ̀bùn tí wọ́n ti mú wá fún-un, wọ́n sì wólẹ̀ níwájú rẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 43

Jẹ́nẹ́sísì 43:17-34