Jẹ́nẹ́sísì 43:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó dáhùn pé, “Ó dára, ẹ má bẹ̀rù, Ọlọ́run yín, àní Ọlọ́run baba yín ni ó fi ìsúra sí inú àpò yín; mo rí owó tí ẹ san gbà.” Nígbà náà ni ó mú Símónì jáde tọ̀ wọ́n wá.

Jẹ́nẹ́sísì 43

Jẹ́nẹ́sísì 43:14-32