Jẹ́nẹ́sísì 43:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì tún mú owó mìíràn lọ́wọ́ láti fi ra oúnjẹ. A ò mọ ẹni tí ó fi owó wa sí ẹnu àpò.

Jẹ́nẹ́sísì 43

Jẹ́nẹ́sísì 43:15-28