Jẹ́nẹ́sísì 42:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nigbà náà ni mẹ́wàá nínú àwọn arákùnrin Jósẹ́fù sọ̀kalẹ̀ lọ sí Éjíbítì láti ra ọkà.

Jẹ́nẹ́sísì 42

Jẹ́nẹ́sísì 42:1-8