Jẹ́nẹ́sísì 42:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mo tí gbọ́ pé ọkà wà ní ilẹ̀ Éjíbítì. Ẹ sọ̀kalẹ̀ lọ sí ibẹ̀ kí ẹ sì rà wá fún wa, kí a má ba à kú.”

Jẹ́nẹ́sísì 42

Jẹ́nẹ́sísì 42:1-6