Jẹ́nẹ́sísì 41:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn wọn ni síírí ọkà méje mìíràn yọ, wọn kò yó'mọ, afẹ́fẹ́ ìlà oòrùn ti rẹ̀ ẹ́ dànù.

Jẹ́nẹ́sísì 41

Jẹ́nẹ́sísì 41:1-7