Jẹ́nẹ́sísì 41:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn màlúù méje tí kò sanra, tí kò sì rẹwà tí ó jáde gbẹ̀yìn jẹ́ ọdún méje, bẹ́ẹ̀ náà ni siiri ọkà méje tí kò dára, tí afẹ́fẹ́ ìlà oòrun ti rẹ̀ dànù tan: Wọn jẹ́ ọdún méje tí ìyàn yóò fi mú.

Jẹ́nẹ́sísì 41

Jẹ́nẹ́sísì 41:17-33