Jẹ́nẹ́sísì 41:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn màlúù méje ti ó dára jẹ́ ọdún méje, ṣiiri ọkà méje tí ó dára náà sì jẹ́ ọdún méje: ọ̀kan ṣoṣo ni wọn, àlá kan náà ni.

Jẹ́nẹ́sísì 41

Jẹ́nẹ́sísì 41:21-34