Jẹ́nẹ́sísì 41:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó sì ti túmọ̀ àlá wọ̀nyí náà ni ohun gbogbo rí. A dá mi padà sí ipò mi, a sì ṣo ọkùnrin keji kọ́ sórí òpó.”

Jẹ́nẹ́sísì 41

Jẹ́nẹ́sísì 41:11-20