Jẹ́nẹ́sísì 40:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jósẹ́fù wí fún-un pé, “Èyí ni ìtumọ̀ àlá rẹ. Ẹ̀ka mẹ́ta náà dúró fún ọjọ́ mẹ́ta.

Jẹ́nẹ́sísì 40

Jẹ́nẹ́sísì 40:7-17