Jẹ́nẹ́sísì 40:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ife Fáráò sì wà lọ́wọ́ mi, mo sì mú àwọn èṣo àjàrà náà, mo sì fún un sínú ife Fáráò, mo sì gbé ife náà fún Fáráò.”

Jẹ́nẹ́sísì 40

Jẹ́nẹ́sísì 40:2-12