Jẹ́nẹ́sísì 38:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì tún bí ọmọkùnrin mìíràn, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Ṣélà. Ní Késíbù ni ó wà nígbà tí ó bí i.

Jẹ́nẹ́sísì 38

Jẹ́nẹ́sísì 38:4-15