Jẹ́nẹ́sísì 38:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì tún lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin, ó sì sọ orúkọ rẹ̀ ní Ónánì.

Jẹ́nẹ́sísì 38

Jẹ́nẹ́sísì 38:2-5