Jẹ́nẹ́sísì 38:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Júdà sì pàdé ọmọbìnrin Kénánì kan níbẹ ẹni ti orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Súà. Ó sì fi ṣe aya, ó sì bá a lò pọ̀;

Jẹ́nẹ́sísì 38

Jẹ́nẹ́sísì 38:1-10