Jẹ́nẹ́sísì 37:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì dáhùn pé, “Àwọn arákùnrin mi ni mò ń wá, ǹjẹ́ o mọ ibi tí wọ́n wà pẹ̀lú agbo ẹran?”

Jẹ́nẹ́sísì 37

Jẹ́nẹ́sísì 37:8-17