Jẹ́nẹ́sísì 37:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkùnrin kan sì rí i tí ó ń rìn kiri inú pápá, ó sì bi í pé, “Kín ni ò ń wá?”

Jẹ́nẹ́sísì 37

Jẹ́nẹ́sísì 37:6-16