Jẹ́nẹ́sísì 34:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ jẹ́ kí a máa ṣe ìgbéyàwó láàrin ara wa, kí àwọn ọmọ yín kó máa fẹ́ àwọn ọmọ wa.

Jẹ́nẹ́sísì 34

Jẹ́nẹ́sísì 34:8-17