Jẹ́nẹ́sísì 34:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hámórì sì bá wọn sọ̀rọ̀ pé, “Ọkàn ọmọ mi Ṣékémù fà sí ọmọ rẹ. Jọ̀wọ́ fi fún un gẹ́gẹ́ bí aya.

Jẹ́nẹ́sísì 34

Jẹ́nẹ́sísì 34:3-12