Jẹ́nẹ́sísì 34:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n kó màlúù wọn àti agbo ẹran wọn àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, àti ohun gbogbo tí ó wà nínú ìlú àti ní oko.

Jẹ́nẹ́sísì 34

Jẹ́nẹ́sísì 34:27-31