Jẹ́nẹ́sísì 34:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ Jákọ́bù sì wọlé àwọn tí a pa, wọ́n sì kó ẹrù ìlú tí a ti ba ògo arábìnrin wọn jẹ́.

Jẹ́nẹ́sísì 34

Jẹ́nẹ́sísì 34:24-31