Jẹ́nẹ́sísì 32:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ó rò ó nínú rẹ̀ pé, “Bí Ísọ̀ bá kọjú ogun sí ìpín kan, ìpín kejì yóò sá àsálà.”

Jẹ́nẹ́sísì 32

Jẹ́nẹ́sísì 32:7-10