Jẹ́nẹ́sísì 32:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Jákọ́bù rí wọn, ó wí pé, “Àgọ́ Ọlọ́run nìyi!” Ó sì pe orúkọ ibẹ̀ ni Máhánáímù.

Jẹ́nẹ́sísì 32

Jẹ́nẹ́sísì 32:1-12