Jẹ́nẹ́sísì 32:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jákọ́bù sì ń bá ọ̀nà tirẹ̀ lọ, àwọn ańgẹ́lì Ọlọ́run sì pàdé rẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 32

Jẹ́nẹ́sísì 32:1-11