Jẹ́nẹ́sísì 32:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jọ̀wọ́ Olúwa gbà mí lọ́wọ́ Ísọ̀ arákùnrin mi, nítorí ẹ̀rù ń bà mí pé yóò wá dojú ìjà kọ mí àti àwọn ìyàwó pẹ̀lú àwọn ọmọ mi.

Jẹ́nẹ́sísì 32

Jẹ́nẹ́sísì 32:10-20