Jẹ́nẹ́sísì 32:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kò tilẹ̀ yẹ fún àánú àti òtítọ́ tí o ń fi hàn fún ìránṣẹ́ rẹ. Nítorí pé, kìkì ọ̀pá mi ni mo mu kúrò ni ilé kọjá Jọ́dánì yìí, ṣùgbọ́n nísin yìí, èmi ti di ẹgbẹ́ méjì.

Jẹ́nẹ́sísì 32

Jẹ́nẹ́sísì 32:6-20