Jẹ́nẹ́sísì 31:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Rákélì sì gbé àwọn òrìṣà náà sínú gàárì ràkunmí, ó sì jókòó lé e lórí. Lábánì sì wá gbogbo inú àgọ́, kò sì rí ohunkóhun.

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:26-37